Translation

Encrypt your submission. Open the terminal and enter this gpg command:
0/700
Context English Yoruba State
Using Tor2Web to connect to SecureDrop will not protect your anonymity. Lílo Tor2Web láti ṣe-ìṣàsopọ̀ sí SecureDrop kò ní fi ààbò bo àìlórúkọọ̀ rẹ.
It could be possible for anyone monitoring your Internet traffic (your government, your Internet provider), to identify you. Ó ṣe é ṣe fún ẹnikẹ́ni láti máa ṣọ́ bí o ti ṣe ń lo Ayélujára (ìjọbaà rẹ, apèsè Ayélujáraà rẹ), láti dá ọ mọ̀.
We strongly advise you to use the Tor Browser instead. A <lágbára>fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ rọ̀ ọ́ </lágbára> kí o kúkú lo
aṣàwáríkiri Tor  náà.
You Should Use Tor Browser Ó Yẹ Kí O Lo Aṣàwáríkiri Tor
If you are not using Tor Browser, you may not be anonymous. Bí o kò bá lo Aṣàwáríkiri Tor, o lè máà wà ní ipò àìlórúkọ.
If you want to submit information to SecureDrop, we strongly advise you to install Tor Browser and use it to access our site safely and anonymously. Bí o bá fẹ́ ṣe-àfisílẹ̀ ìwífún sí oríi SecureDrop, a <lágbára>rọ̀ ọ́</lágbára> kí o fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ, kí o sì lò ó láti fi wọ inú ibùdóo wa pẹ̀lú ààbò àti ìpamọ́ ipò àìlórúkọ.
Copy and paste the following address into your browser and follow the instructions to download and install Tor Browser: Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ:
If there is a chance that downloading Tor Browser raises suspicion and your mail provider is less likely to be monitored, you can send a mail to
gettor@torproject.org
and a bot will answer with instructions. Bí gbígba Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ bá mú ìfura dání àti pé kò sí àrídájú wípé apèsè ìfìwéránṣẹ́ (ímeèlì) rẹ wà ní abẹ́ ìṣọ́, o lè kọ̀wé sí
gettor@torproject.org
, tí ẹ̀rọ yóò sì dáhùn pẹ̀lú ìtọ́nà ohun tí o ó ṣe.
Why download the team's public key? Kí ló dé tí ó fi yẹ kí akọ̀ròyìn ó gba kọ́kọ́rọ́ọ gbogboògbò sílẹ̀ sórí ẹ̀rọ?
SecureDrop encrypts files and messages after they are submitted. Encrypting messages and files before submission can provide an extra layer of security before your data reaches the SecureDrop server. SecureDrop máa ń yí odù fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ padà fún ààbò ní kété tí o bá ti ṣe-àfisílẹ̀. Yíyí iṣẹ́-ìjẹ́ àti fáìlì padà-sì-odù-ààbò kí o tó ó ṣe-àfisílẹ̀ leè pèsè àlékún ìpele ààbò kí dátà rẹ ó dé apèsè SecureDrop náà.
If you are already familiar with the GPG encryption software, you may wish to encrypt your submissions yourself. To do so: Bí o bá mọ iṣẹ́-àrídìmú ìyí-data-padà-sí-odù-fún-ààbò GPG, ó lè hùn ọ́ kí o yí odù àfisílẹ̀ rẹ padà fún ààbò fúnraà rẹ. Láti ṣe bẹ́ẹ̀:
Download the public key. It will be saved to a file called:

{submission_key_fpr_filename}

Ṣàgbàsílẹ̀ kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò náà. Fáìlì àyọkà náà ni kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò pẹ̀lú <odù>.asc</odù>
Import it into your GPG keyring. Kó o wọlé sínúu GPG rẹ pẹ̀lú òrùkakọ́kọ́rọ́.
If you are using Tails, you can double-click the .asc file you just downloaded and it will be automatically imported to your keyring. Bí o bá ń lo Tails, o lè tẹ <odù>.asc</odù> fáìlì tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbàsílẹ̀ẹ rẹ̀ lẹ́ẹ̀-mejì yóò sì di kíkó wọlé sí òrùkakọ́kọ́rọ́ọ̀ rẹ fúnra rẹ̀.
If you are using macOS or Linux, open the terminal. You can import the key with:
gpg --import /path/to/{submission_key_fpr_filename}
Bí o bá ń lo Mac/Linux, ṣí terminal. O leè kó kọ́kọ́rọ́ wọlé pẹ̀lú <odù>gpg --
kówọlé/ipaọ̀nà/sí/kọ́kọ́rọ́.asc</odù>.
Encrypt your submission. Open the terminal and enter this gpg command:
gpg --recipient '{submission_key_fpr}' --encrypt /path/to/submission
Upload your encrypted submission. It will have the same filename as the unencrypted file, with .gpg at the end (e.g. internal_memo.pdf.gpg) Ṣàgbésí àfisílẹ̀ tí odùu rẹ̀ ti yí padà fún ààbò. Yóò ní orúkọ fáìlì kan náà bíi fáìlì tí a kò yí odùu rẹ̀ padà fún ààbò, pẹ̀lú .gpg ní ẹ̀yìn (fún àpẹẹrẹ <odù>àwòránan_roswell.pdf.gpg</odù>)
Important: If you wish to remain anonymous, do not use GPG to sign the encrypted file (with the --sign or -s flag) as this will reveal your GPG identity to us. <lágbára>Olobó:</lágbára> Bí o bá fẹ́ wà ní ipò àìlórúkọ, <lágbára>o kò gbọdọ̀ </lágbára> lo GPG láti fi ọwọ́ bọ fáìlì náà tí o yí odùu rẹ̀ padà fún ààbò (pẹ̀lú <odù>--fi ọwọ́ bọ</odù> tàbí <odù>-s</odù> àsíá) nítorí èyí yóò fi ìdánimọ̀ GPG rẹ hàn wá.
Back to submission page Padà sí ojú-ìwé asàfisílẹ̀

Loading…

No matching activity found.

Browse all component changes

Glossary

English Yoruba
No related strings found in the glossary.

Source information

Flags
python-brace-format, python-format
String age
6 months ago
Source string age
6 months ago
Translation file
securedrop/translations/yo/LC_MESSAGES/messages.po, string 297