Translation

Forgot your codename?
22/210
Context English Yoruba State
Thanks! We received your message. O ṣeun! A rí iṣẹ́-ìjẹ́ẹ̀ rẹ.
Thanks! We received your document. O ṣeun! A rí ìwé-ìrídìíì rẹ.
Thanks! We received your message and document. O ṣeun! A rí iṣẹ́-ìjẹ́ àti ìwé-ìrídìíì rẹ.
Reply deleted Èsì ti parẹ́
All replies have been deleted Gbogbo èsì ti parẹ́
Sorry, that is not a recognized codename. Ó dun'ni, ìyẹn kì í ṣe orúkọ-odù tí a dá mọ̀.
Protecting Journalists and Sources Ìdáàbòbo Oníròyìn àti àwọn Orísun ìròyìn
SecureDrop Home
We're sorry, our SecureDrop is currently offline.
Please try again later. Check our website for more information.
LOG OUT FÀṢẸ JÁDE
Server error Ìsopọ̀ kùnà
Sorry, the website encountered an error and was unable to complete your request. Ó dun'ni, ibùdó-ìtakùn ko ìṣòro kan, kò sì leè parí ìbéèrè rẹ.
Look up a codename... Ṣàwárí orúkọ-odù kan...
Thank you for sending this information to us. Please check back later for replies. O ṣeun tí o fi ìwífún yìí ránṣẹ́ sí wá. Jọ̀wọ́ padà wá síbí fún èsì.
Forgot your codename? O gbàgbé orúkọ-odù rẹ?
Powered by Àgbékalẹ̀ẹ
Please note: Sharing sensitive documents may put you at risk, even when using Tor and SecureDrop. Jọ̀wọ́ kíyèsíi: Pínpín ìwé-ìrídìí tí ó ní àlàyé ohun ìkọ̀kọ̀ nípa araà rẹ leè kó ọ sí ewu, kódà bí o bá ń lo Tor àti SecureDrop.
SecureDrop is a project of Freedom of the Press Foundation. Freedom of the Press Foundation ni ó ṣe iṣẹ́-àkànṣe SecureDrop.
Welcome Káàbọ̀
Please either write this codename down and keep it in a safe place, or memorize it. Jọ̀wọ́ kọ orúkọ-odù yìí sílẹ̀ kí o fi pamọ́ sí ibìkan, tàbí kí o há a sí agbárí.
This codename is what you will use in future visits to receive messages from our team in response to what you submit on the next screen. Orúkọ-odù yìí ni ohun tí o ó lò ní ọjọ́ iwájú tí o ó fi máa gba iṣẹ́-ìjẹ́ láti ọwọ́ọ àwọn oníròyìn-in wa ní ìfèsì sí ohun tí o kọ sí wa.
Because we do not track users of our SecureDrop
service, in future visits, using this codename will be the only way we have to communicate with you should we have
questions or are interested in additional information. Unlike passwords, there is no way to retrieve a lost codename.
Nítorí pé a kò ń tọpa àwọn tó ń lo SecureDrop
wa,
ní ọjọ́ iwájú, orúkọ-odù yìí ni yóò jẹ́ ọ̀nà kan ṣoṣo tí a ó máa fi bá ọ tàkùrọ̀sọ nígbàkúùgbà tí a bá ní
àwọn
ìbéèrè tàbí bí a bá fẹ́ àlàyé sí i. Kò jọ ti ọ̀rọ̀-ìfiwọlé, kò sí bí o ti lè ṣe rí orúkọ-odù tí o bá sọnù gbà padà.
Kò jọ ti ọ̀rọ̀-ìfiwọlé, kò sí bí o ti lè ṣe rí orúkọ-odù tí o bá sọnù gbà padà.
SUBMIT DOCUMENTS TARI ÌWÉ-ÌRÍDÌÍ
Your Tor Browser's Security Level is too low. Use the   button in your browser’s toolbar to change it. Tor Browser rẹ<lágbára>kò ní Ààtò Ààbò tó tó. Lo bọ́tììnì   ní oríi pátákòirinṣẹ́ aṣàwáríkiriì rẹ láti pààrọ rẹ̀.
It is recommended to use Tor Browser to access SecureDrop: Learn how to install it, or ignore this warning to continue. A fi òǹtẹ̀ lu Aṣàwáríkiriì Tor fún ọ bí o bá fẹ́ lo SecureDrop: Kọ́ bí o ṣe lè fi sí orí ẹ̀rọ, tàbí kí o tẹ̀síwájú láì ka ìkìlọ̀ yìí kún.
It is recommended you use the desktop version of Tor Browser to access SecureDrop, as Orfox does not provide the same level of security and anonymity as the desktop version. Learn how to install it, or ignore this warning to continue. <lágbára>A gbà ọ́ níyànjú kí o lo ẹ̀da Aṣàwáríkiri Tor fún ẹ̀rọ àgbélétábìlì fún SecureDrop, nítorí Orfox kò pèsè ààbò àti àìlórúkọ bíi ẹ̀dà ti ẹ̀rọ-àgbélétábìlì.</lágbára> Kọ́ bí o ṣe lè fi sí orí ẹ̀rọ, tàbí kí o tẹ̀síwájú láì ka ìkìlọ̀ yìí kún.
First submission Àfisílẹ̀ àkọ́kọ́
First time submitting to our SecureDrop? Start here. Ìgbà àkọ́kọ́ tí o ó lo SecureDrop wa? Bẹ̀rẹ̀ níbí.
GET STARTED BẸ̀RẸ̀
Return visit Àbẹ̀wò padà

Loading…

User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

Forgot your codename?
O gbàgbé orúkọ-odù rẹ?
a year ago
Browse all component changes

Glossary

English Yoruba
No related strings found in the glossary.

Source information

Flags
python-brace-format, python-format
String age
3 years ago
Source string age
3 years ago
Translation file
securedrop/translations/yo/LC_MESSAGES/messages.po, string 230