Translation

We strongly advise you to use the Tor bBrowser instead.
We strongly advise you to use the Tor Browser instead.
138/1290
Context English Yoruba State
Important
Pàtàkì!
You were logged out due to inactivity. Click the  New Identity button in your Tor Browser's toolbar before moving on. This will clear your Tor Browser activity data on this device.

Why is there a warning about Tor2Web?
Èé ṣe tí ìkìlọ̀ ṣe wà nípa Tor2Web?
Using Tor2Web to connect to SecureDrop will not protect your anonymity.
Lílo Tor2Web láti ṣe-ìṣàsopọ̀ sí SecureDrop kò ní fi ààbò bo àìlórúkọọ̀ rẹ.
It could be possible for anyone monitoring your Internet traffic (your government, your Internet provider), to identify you.
Ó ṣe é ṣe fún ẹnikẹ́ni láti máa ṣọ́ bí o ti ṣe ń lo Ayélujára (ìjọbaà rẹ, apèsè Ayélujáraà rẹ), láti dá ọ mọ̀.
We strongly advise you to use the Tor Browser instead.
A <lágbára>fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ rọ̀ ọ́ </lágbára> kí o kúkú lo
aṣàwáríkiri Tor  náà.
You Should Use Tor Browser
Ó Yẹ Kí O Lo Aṣàwáríkiri Tor
If you are not using Tor Browser, you may not be anonymous.
Bí o kò bá lo Aṣàwáríkiri Tor, o lè máà wà ní ipò àìlórúkọ.
If you want to submit information to SecureDrop, we strongly advise you to install Tor Browser and use it to access our site safely and anonymously.
Bí o bá fẹ́ ṣe-àfisílẹ̀ ìwífún sí oríi SecureDrop, a <lágbára>rọ̀ ọ́</lágbára> kí o fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ, kí o sì lò ó láti fi wọ inú ibùdóo wa pẹ̀lú ààbò àti ìpamọ́ ipò àìlórúkọ.
Copy and paste the following address into your browser and follow the instructions to download and install Tor Browser:
Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ:
If there is a chance that downloading Tor Browser raises suspicion and your mail provider is less likely to be monitored, you can send a mail to
gettor@torproject.org
and a bot will answer with instructions.
Bí gbígba Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ bá mú ìfura dání àti pé kò sí àrídájú wípé apèsè ìfìwéránṣẹ́ (ímeèlì) rẹ wà ní abẹ́ ìṣọ́, o lè kọ̀wé sí
gettor@torproject.org
, tí ẹ̀rọ yóò sì dáhùn pẹ̀lú ìtọ́nà ohun tí o ó ṣe.

Loading…

None

Source string changed

SecureDrop / SecureDropYoruba

We strongly advise you to use the Tor bBrowser instead.
3 weeks ago
Browse all component changes

Things to check

XML markup

XML tags in translation do not match source

Mismatching line breaks

Number of new lines in translation does not match source

Reset

Glossary

English Yoruba
No related strings found in the glossary.

Source information

Labels
No labels currently set.
Flags
python-brace-format, python-format
Source string age
3 weeks ago
Translation file
securedrop/translations/yo/LC_MESSAGES/messages.po, string 249