Translation
Sorry, we couldn't locate what you requested.
42/450
Context English Yoruba State
You can submit any kind of file, a message, or both. O leè Ṣe-àfisílẹ̀ onírúurú fáìlì, iṣẹ́-ìjẹ́, tàbí méjèèjì.
Submit Messages Ṣe-àfisílẹ̀ Fáìlì tàbí Iṣẹ́-ìjẹ́
Maximum upload size: 500 MB
Read Replies Ka àwọn Èsì
You have received a reply. To protect your identity in the unlikely event someone learns your codename, please delete all replies when you're done with them. This also lets us know that you are aware of our reply. You can respond by submitting new files and messages above. O ti ní èsì kan. Láti dáàbò bo ìdánimọ̀ rẹ bí ẹnìkan bá jí orúkọ-odù rẹ, jọ̀wọ́ pa gbogbo èsì rẹ́ bí o bá bùṣe pẹ̀lúu wọn. Èyí tún mú wa mọ̀ wípé o mọ̀ sí èsìi wa. O lè fèsì nípa fífi fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ tuntun sílẹ̀ sókè.
Delete this reply? Pa èsì yìí rẹ́?
DELETE ALL REPLIES PA GBOGBO ÈSÌ RẸ́
Are you finished with the replies? Ṣé o ti parí pẹ̀lú àwọn èsì náà?
YES, DELETE ALL REPLIES BẸ́Ẹ̀NI, PA GBOGBO ÈSÌ RẸ́
NO, NOT YET RÁRÁ, KÒÌ YÁ
— No Messages —
Page not found Ojú-ìwé ò jẹ́ rírí
Sorry, we couldn't locate what you requested. Ó dun'ni, a kò leè rí ohun tí o béèrè fún.
Important Pàtàkì!
You were logged out due to inactivity. Click the  New Identity button in your Tor Browser's toolbar before moving on. This will clear your Tor Browser activity data on this device.
Why is there a warning about Tor2Web? Èé ṣe tí ìkìlọ̀ ṣe wà nípa Tor2Web?
Using Tor2Web to connect to SecureDrop will not protect your anonymity. Lílo Tor2Web láti ṣe-ìṣàsopọ̀ sí SecureDrop kò ní fi ààbò bo àìlórúkọọ̀ rẹ.
It could be possible for anyone monitoring your Internet traffic (your government, your Internet provider), to identify you. Ó ṣe é ṣe fún ẹnikẹ́ni láti máa ṣọ́ bí o ti ṣe ń lo Ayélujára (ìjọbaà rẹ, apèsè Ayélujáraà rẹ), láti dá ọ mọ̀.
We strongly advise you to use the Tor Browser instead. A <lágbára>fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ rọ̀ ọ́ </lágbára> kí o kúkú lo
aṣàwáríkiri Tor  náà.
You Should Use Tor Browser Ó Yẹ Kí O Lo Aṣàwáríkiri Tor
If you are not using Tor Browser, you may not be anonymous. Bí o kò bá lo Aṣàwáríkiri Tor, o lè máà wà ní ipò àìlórúkọ.
If you want to submit information to SecureDrop, we strongly advise you to install Tor Browser and use it to access our site safely and anonymously. Bí o bá fẹ́ ṣe-àfisílẹ̀ ìwífún sí oríi SecureDrop, a <lágbára>rọ̀ ọ́</lágbára> kí o fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ, kí o sì lò ó láti fi wọ inú ibùdóo wa pẹ̀lú ààbò àti ìpamọ́ ipò àìlórúkọ.
Copy and paste the following address into your browser and follow the instructions to download and install Tor Browser: Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ:
If there is a chance that downloading Tor Browser raises suspicion and your mail provider is less likely to be monitored, you can send a mail to
gettor@torproject.org
and a bot will answer with instructions. Bí gbígba Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ bá mú ìfura dání àti pé kò sí àrídájú wípé apèsè ìfìwéránṣẹ́ (ímeèlì) rẹ wà ní abẹ́ ìṣọ́, o lè kọ̀wé sí
gettor@torproject.org
, tí ẹ̀rọ yóò sì dáhùn pẹ̀lú ìtọ́nà ohun tí o ó ṣe.
Why download the team's public key? Kí ló dé tí ó fi yẹ kí akọ̀ròyìn ó gba kọ́kọ́rọ́ọ gbogboògbò sílẹ̀ sórí ẹ̀rọ?
SecureDrop encrypts files and messages after they are submitted. Encrypting messages and files before submission can provide an extra layer of security before your data reaches the SecureDrop server. SecureDrop máa ń yí odù fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ padà fún ààbò ní kété tí o bá ti ṣe-àfisílẹ̀. Yíyí iṣẹ́-ìjẹ́ àti fáìlì padà-sì-odù-ààbò kí o tó ó ṣe-àfisílẹ̀ leè pèsè àlékún ìpele ààbò kí dátà rẹ ó dé apèsè SecureDrop náà.
If you are already familiar with the GPG encryption software, you may wish to encrypt your submissions yourself. To do so: Bí o bá mọ iṣẹ́-àrídìmú ìyí-data-padà-sí-odù-fún-ààbò GPG, ó lè hùn ọ́ kí o yí odù àfisílẹ̀ rẹ padà fún ààbò fúnraà rẹ. Láti ṣe bẹ́ẹ̀:
Download the public key. It will be saved to a file called:
{submission_key_fpr_filename}
Ṣàgbàsílẹ̀ kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò náà. Fáìlì àyọkà náà ni kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò pẹ̀lú <odù>.asc</odù>
Loading…
User avatar OmoYooba
New translation
SecureDrop / SecureDropYoruba
Sorry, we couldn't locate what you requested.
Ó dun'ni, a kò leè rí ohun tí o béèrè fún.
a year ago
Browse all component changes
Glossary
English Yoruba
No related strings found in the glossary.
Source information
Screenshot context
Flags
python-brace-format, python-format
String age
3 years ago
Source string age
3 years ago
Translation file
securedrop/translations/yo/LC_MESSAGES/messages.po, string 278