User avatar

Adéṣínà Ayẹni

@OmoYooba Joined on Sept. 19, 2019

281 translations

Project Translated Untranslated Untranslated words Checks Suggestions Comments
SecureDrop Some of the components within this project have alerts. 62% 4,998 44,149 436 218 132

Nothing to list here.

Nothing to list here.

Daily activity

Daily activity

Weekly activity

Weekly activity
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

Back to submission page
Padà sí ojú-ìwé asàfisílẹ̀
a year ago
User avatar OmoYooba

Translation changed

SecureDrop / SecureDropYoruba

If you are using Tails, you can double-click the .asc file you just downloaded and it will be automatically imported to your keyring.
Bí o bá ń lo Tails, o lè tẹ <odù>.asc</odù> fáìlì tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbàsílẹ̀ẹ rẹ̀ lẹ́ẹ̀-mejì yóò sì di kíkó wọlé sí òrùkakọ́kọ́rọ́ọ̀ rẹ fúnra rẹ̀.
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

If you are using Tails, you can double-click the .asc file you just downloaded and it will be automatically imported to your keyring.
Bí o bá ń lo Tails, o lè tẹ <odù>.asc</odù> fáìlì tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbàsílẹ̀ẹ rẹ̀ lẹ́ẹ̀mejì yóò sì di kíkó wọlé sí òrùkakọ́kọ́rọ́ọ̀ rẹ fúnra rẹ̀.
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

Import it into your GPG keyring.
Kó o wọlé sínúu GPG rẹ pẹ̀lú òrùkakọ́kọ́rọ́.
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

If you are already familiar with the GPG encryption software, you may wish to encrypt your submissions yourself. To do so:
Bí o bá mọ iṣẹ́-àrídìmú ìyí-data-padà-sí-odù-fún-ààbò GPG, ó lè hùn ọ́ kí o yí odù àfisílẹ̀ rẹ padà fún ààbò fúnraà rẹ. Láti ṣe bẹ́ẹ̀:
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

SecureDrop encrypts files and messages after they are submitted. Encrypting messages and files before submission can provide an extra layer of security before your data reaches the SecureDrop server.
SecureDrop máa ń yí odù fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ padà fún ààbò ní kété tí o bá ti ṣe-àfisílẹ̀. Yíyí iṣẹ́-ìjẹ́ àti fáìlì padà-sì-odù-ààbò kí o tó ó ṣe-àfisílẹ̀ leè pèsè àlékún ìpele ààbò kí dátà rẹ ó dé apèsè SecureDrop náà.
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

If there is a chance that downloading Tor Browser raises suspicion and your mail provider is less likely to be monitored, you can send a mail to
gettor@torproject.org
and a bot will answer with instructions.
Bí gbígba Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ bá mú ìfura dání àti pé kò sí àrídájú wípé apèsè ìfìwéránṣẹ́ (ímeèlì) rẹ wà ní abẹ́ ìṣọ́, o lè kọ̀wé sí
gettor@torproject.org
, tí ẹ̀rọ yóò sì dáhùn pẹ̀lú ìtọ́nà ohun tí o ó ṣe.
a year ago
User avatar OmoYooba

Translation changed

SecureDrop / SecureDropYoruba

Copy and paste the following address into your browser and follow the instructions to download and install Tor Browser:
Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ.:
a year ago
User avatar OmoYooba

New translation

SecureDrop / SecureDropYoruba

Copy and paste the following address into your browser and follow the instructions to download and install Tor Browser:
Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ.
a year ago
User avatar OmoYooba

Translation changed

SecureDrop / SecureDropYoruba

If you want to submit information to SecureDrop, we strongly advise you to install Tor Browser and use it to access our site safely and anonymously.
Bí o bá fẹ́ ṣe-àfisílẹ̀ ìwífún sí oríi SecureDrop, a <lágbára>fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ rọ̀ ọ́</lágbára> kí o fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ, kí o sì lò ó láti fi wọ inú ibùdóo wa pẹ̀lú ààbò àti ìpamọ́ ipò àìlórúkọ.
a year ago
Browse all changes for user